Je ki o kan daradara ki o to po Ogi/Koko/Akamu! O le ran ilera re lowo! (PROPERLY FERMENT AND PREPARE YOUR OGI/KOKO/AKAMU/PAP! IT CAN SAVE YOUR LIFE!)
Feed the Future Innovation Lab for Food Security Policy Nigeria Agricultural Policy Project September 2018 Oluwatoyin Ademola Saweda Onipede Liverpool-Tasie Adewale Obadina Felicia Wu & Nikita Saha Turna Kini Mycotoxins (maele lati inu elu)? Mycotoxins j ẹ aw ọ n nkan ti o lewu (majele) ti o wa a nipas ẹ ori ṣ iri ṣ i elu(fungi). Majele (mycotoxin) lati inu elu ninu awon ounje wa j ẹ idiwo tabi idena ti o lagbara fun ilera eniyan ati pe agbado j ẹ ọ kan ninu aw ọ n irugbin ti o ni arun yin ni orile ede Naijiria. Source: Authors Ọ p ọ l ọ p ọ aw ọ n majele (mycotoxins) w ọ nyi wa, ṣ ugb ọ n aw ọ n meji ni o j ẹ gboogi ti nyo ilera eniyan lenu. Awon mejeji ni aflatoxins ati fumonisins . W ọ n wa nipas ẹ elu ti o je iru tii Aspergillus ati Fusarium . Kilode ti aw ọ n majele inu elu yi (mycotoxins) lewu? Aw ọ n majele yi (mycotoxins) yi lewu nitori pupo ninu w ọ n ni oro ...